*Music Video* @qdot_alagbe – Ibere (Question) + lyrics

 

LYRICS

[Intro]
Antras on the beat
Qdot l’oruko mi hun
Alagbe…
Antras joo

[Chorus]
Ki lo pa iya ijebu
Ibeere (2ce)
Won n bi mi lere
Ibeere (2ce)
Shey eleyi ri owo s’aye sha
Ibeere (2ce)
Nibo lo ti ri owo na
Ibeere (3ce)
O n bi mi o
Ibeere (2ce)
O ma n bi mi o
Ibeere (2ce)
U la la la la he he uh
Ibeere (2ce)
U la la la la he he uh
Ibeere (2ce)

[Verse 1]
Mo ko gold s’orun
Won ni panda ni
Ba lo gucci versace
Won a ni won ya ni
Adete mi fe je iresi
Oyinbo yin n su’kun n geesi
Won fe mo idi abajo mi
Baba loke baba alajo mi
Foolish people, foolish question
Nibo lo ti ri owo, ta lo lo’wo
Won lo se eniyan fun ogun owo
Alapa ma sise pofolo
E ye bi mi lere mo o
Foolish people
Ki e ye bi mi leere mo o…
Iku to pa iya ijebi

[Repeat Chorus]
Ki lo pa iya ijebu
Ibeere (2ce)
Won n bi mi lere
Ibeere (2ce)
Shey eleyi ri owo s’aye sha
Ibeere (2ce)
Nibo lo ti ri owo na
Ibeere (3ce)
O n bi mi o
Ibeere (2ce)
O ma n bi mi o
Ibeere (2ce)
U la la la la he he uh
Ibeere (2ce)
U la la la la he he uh
Ibeere (2ce)

[Verse 2]
Oro mi lan n so ni gboro
Gongo a so ni igboro
Oro mi lan n so lo ni gboro
Gongo a so ni igboro
Baba bi ke po’se
E je ko ye won pe enu o shey
Regular n shey bi vip
Bi olode n shey bi CIP
E duro nibe
Ki le di, kuku ninu EOD
Hey…
Agbo mi to tadi m’eyin agbara lo lo mu wa
Bi agbo yin ba tadi m’eyin tipper lo ma pa
(Speaking in tongue)

[REpeat Chorus]
Ki lo pa iya ijebu
Ibeere (2ce)
Won n bi mi lere
Ibeere (2ce)
Shey eleyi ri owo s’aye sha
Ibeere (2ce)
Nibo lo ti ri owo na
Ibeere (3ce)
O n bi mi o
Ibeere (2ce)
O ma n bi mi o
Ibeere (2ce)
U la la la la he he uh
Ibeere (2ce)
U la la la la he he uh
Ibeere (2ce)

(Speaking in tongue)
Ogun orun ba won wi, ba won ja

[Repeat Chorus]
Ki lo pa iya ijebu
Ibeere (2ce)
Won n bi mi lere
Ibeere (2ce)
Shey eleyi ri owo s’aye sha
Ibeere (2ce)
Nibo lo ti ri owo na
Ibeere (3ce)
O n bi mi o
Ibeere (2ce)
O ma n bi mi o
Ibeere (2ce)
U la la la la he he uh
Ibeere (2ce)
U la la la la he he uh
Ibeere (2ce)

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s